Native Bible

1 Chronicles 1:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kuṣi sì bí Nimrodu ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.

1 Chronicles 1:10 in English

1 Chronicles 1:10 · Berean Standard Bible

Cush was the father of Nimrod, who began to be a mighty one * on the earth.

Context

8Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti, àti Kenaani. 9Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka. Àwọn ọmọ Raama: Ṣeba àti Dedani. 10Kuṣi sì bí Nimrodu ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. 11Ejibiti sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu, 12Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.