Native Bible

Zechariah 3:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó sì fi Joṣua olórí àlùfáà hàn mí, ó dúró níwájú angẹli Olúwa, Satani sí dúró lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ̀ láti kọjú ìjà sí i.

Zechariah 3:1 in English

Zechariah 3:1 · Berean Standard Bible

Then the angel showed me Joshua the high priest standing before the angel * of the LORD, with Satan * standing at his right hand to accuse him.

Context

1Ó sì fi Joṣua olórí àlùfáà hàn mí, ó dúró níwájú angẹli Olúwa, Satani sí dúró lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ̀ láti kọjú ìjà sí i. 2Olúwa si wí fún Satani pé, “Olúwa bá ọ wí ìwọ Satani; àní Olúwa tí ó ti yan Jerusalẹmu, bá ọ wí, igi iná kọ́ ni èyí tí a mú kúrò nínú iná?” 3A sì wọ Joṣua ni aṣọ èérí, ó sì dúró níwájú angẹli náà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.