Native Bible

Romans 15:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kí Ọlọ́run àlàáfíà wà pẹ̀lú gbogbo yín. Àmín.

Romans 15:33 in English

Romans 15:33 · Berean Standard Bible

The God of peace be with all of you. Amen.*

Context

31Kí a lè kó mi yọ kúrò lọ́wọ́ àwọn aláìgbàgbọ́ ní Judea àti kí iṣẹ́ ìránṣẹ́ tí mo ní sí Jerusalẹmu le jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn mímọ́ níbẹ̀, 32kí èmi le fi ayọ̀ tọ̀ yín wa, nípa ìfẹ́ Ọlọ́run, àti kí èmi lè ní ìtura pọ̀ pẹ̀lú yín. 33Kí Ọlọ́run àlàáfíà wà pẹ̀lú gbogbo yín. Àmín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.