Saamu 9:5
Psalms 9:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ ti bá orílẹ̀-èdè wí, Ìwọ sì ti pa ẹni búburú run; Ìwọ ti yọ orúkọ wọn kúrò láé àti láéláé.
Psalms 9:5 in English
Psalms 9:5 · Berean Standard Bible
You have rebuked the nations; You have destroyed the wicked; You have erased their name forever and ever.
Context
3Àwọn ọ̀tá mi pẹ̀yìndà;
wọ́n kọsẹ̀ wọn sì ṣègbé níwájú rẹ. 4Nítorí ìwọ ti di òtítọ́ àti ọ̀ràn mi mú;
ìwọ ti jókòó lórí ìtẹ́ rẹ, láti ṣe ìdájọ́ òdodo. 5Ìwọ ti bá orílẹ̀-èdè wí, Ìwọ sì ti pa ẹni búburú run;
Ìwọ ti yọ orúkọ wọn kúrò láé àti láéláé. 6Ìparun àìlópin ti borí àwọn ọ̀tá,
ìwọ ti fa àwọn ìlú wọn tu;
àní ìrántí wọn sì ti ṣègbé. 7Olúwa jẹ ọba títí láé;
ó ti gbé ìtẹ́ rẹ̀ kalẹ̀ fún ìdájọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.