Saamu 9:2
Psalms 9:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Inú mi yóò dùn, èmi yóò sì yọ̀ nínú rẹ; èmi ó kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ, Ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.
Psalms 9:2 in English
Psalms 9:2 · Berean Standard Bible
I will be glad and rejoice in You; I will sing praise to Your name, O Most High.
Context
1Èmi ó yìn ọ́, Olúwa, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi;
èmi ó sọ ti ìyanu rẹ gbogbo. 2Inú mi yóò dùn, èmi yóò sì yọ̀ nínú rẹ;
èmi ó kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ, Ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ. 3Àwọn ọ̀tá mi pẹ̀yìndà;
wọ́n kọsẹ̀ wọn sì ṣègbé níwájú rẹ. 4Nítorí ìwọ ti di òtítọ́ àti ọ̀ràn mi mú;
ìwọ ti jókòó lórí ìtẹ́ rẹ, láti ṣe ìdájọ́ òdodo.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.