Native Bible

Psalms 89:52 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olùbùkún ní Olúwa títí láé. Àmín àti Àmín.

Psalms 89:52 in English

Psalms 89:52 · Berean Standard Bible

Blessed be the LORD forever! Amen and amen.

Context

50Rántí, Olúwa, bí a ti ń gan àwọn ìránṣẹ́ rẹ; bí èmi ti gbà ní àyà mi láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn, 51ẹ̀gàn tí àwọn ọ̀tá rẹ gàn, Olúwa, tí wọn gan ipasẹ̀ ẹni àmì òróró rẹ. 52Olùbùkún ní Olúwa títí láé. Àmín àti Àmín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.