Saamu 89:27
Psalms 89:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi yóò ṣe é ni àkọ́bí mi, ẹni gíga ju àwọn ọba ayé.
Psalms 89:27 in English
Psalms 89:27 · Berean Standard Bible
I will indeed appoint him as My firstborn, the highest of the kings of the earth.
Context
25Èmi ó gbé ọwọ́ rẹ lórí òkun,
àti ọwọ́ ọ̀tún rẹ lórí àwọn odo ńlá. 26Òun yóò kígbe sí mi pé, ‘Ìwọ ni baba mi, Ọlọ́run mi, àti àpáta ìgbàlà mi!’ 27Èmi yóò ṣe é ni àkọ́bí mi,
ẹni gíga ju àwọn ọba ayé. 28Títí láé ni èmi yóò pa ìfẹ́ dídúró ṣinṣin mọ́ fún un,
àti májẹ̀mú mi pẹ̀lú rẹ̀ yóò dúró gbọingbọin. 29Èmi ó fi ìdí irú-ọmọ rẹ̀ múlẹ̀ títí láé,
àti ìtẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí ọ̀run ti wà láé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.