Saamu 85:5
Psalms 85:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ yóò ha máa bínú sí wa títí láé? Ìwọ yóò ha mú ìbínú rẹ pẹ́ yí gbogbo ìran ká?
Psalms 85:5 in English
Psalms 85:5 · Berean Standard Bible
Will You be angry with us forever? Will You draw out Your anger to all generations?
Context
3Ìwọ fi àwọn ìbínú rẹ sápá kan
ìwọ sì yípadà kúrò nínú ìbínú gbígbóná rẹ. 4Yí wa padà, Ọlọ́run ìgbàlà wa,
kí o sì yí ìbínú rẹ̀ padà kúrò lọ́dọ̀ wa. 5Ìwọ yóò ha máa bínú sí wa títí láé?
Ìwọ yóò ha mú ìbínú rẹ pẹ́ yí gbogbo ìran ká? 6Ìwọ kì yóò ha sọ wá jí padà mọ́,
pé kí àwọn ènìyàn rẹ lè yọ nínú rẹ? 7Fi ìfẹ́ rẹ tí kò le è kùnà hàn wá, Olúwa,
kí o sì fún wa ní ìgbàlà rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.