Native Bible

Psalms 78:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó jẹ́ kí wọn jáde ní ibùdó wọn, yíká àgọ́ wọn.

Psalms 78:28 in English

Psalms 78:28 · Berean Standard Bible

He felled them in the midst of their camp, all around their dwellings.

Context

26Ó mú afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn láti ọ̀run wá ó mú afẹ́fẹ́ gúúsù wá nípa agbára rẹ̀. 27Ó rọ òjò ẹran sílẹ̀ sórí wọn bí erùpẹ̀ ilẹ̀, àti ẹyẹ abìyẹ́ gẹ́gẹ́ bí iyanrìn etí òkun 28Ó jẹ́ kí wọn jáde ní ibùdó wọn, yíká àgọ́ wọn. 29Wọ́n jẹ, wọ́n sì yó jọjọ nítorí ó ti fún wọn ní ohun tí wọn fìtara bẹ̀bẹ̀ fún. 30Ṣùgbọ́n wọn kò kúrò nínú oúnjẹ tí wọn fìtara bẹ̀bẹ̀ fún, nígbà tí oúnjẹ wọn sì wà ní ẹnu wọn,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.