Saamu 74:15
Psalms 74:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ ya orísun omi àti ìṣàn omi; Ìwọ mú kí odò tó ń sàn gbẹ.
Psalms 74:15 in English
Psalms 74:15 · Berean Standard Bible
You broke open the fountain and the flood; You dried up the ever-flowing rivers.
Context
13Ìwọ ni ó la òkun sílẹ̀ nípa agbára rẹ;
ìwọ fọ́ orí ẹ̀mí búburú nínú omi. 14Ìwọ fọ́ orí Lefitani túútúú, o sì fi ṣe oúnjẹ fun àwọn ẹ̀dá tí ń gbé inú ijù
tìrẹ ni ọ̀sán, tìrẹ sì ni alẹ́ pẹ̀lú;
ìwọ fi ìdí oòrùn àti òṣùpá lélẹ̀. 15Ìwọ ya orísun omi àti ìṣàn omi;
Ìwọ mú kí odò tó ń sàn gbẹ. 16Tìrẹ ni ọ̀sán, tìrẹ ni òru pẹ̀lú;
ìwọ yà oòrùn àti òṣùpá. 17Ìwọ pààlà etí ayé;
Ìwọ dá ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ìgbà òtútù.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.