Saamu 71:2
Psalms 71:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbà mí kí o sì tú mi sílẹ̀ nínú òdodo rẹ; dẹ etí rẹ sí mi, kí o sì gbà mí.
Psalms 71:2 in English
Psalms 71:2 · Berean Standard Bible
In Your justice, rescue and deliver me; incline Your ear and save me.
Context
1Nínú rẹ, Olúwa, ni mo ní ààbò;
má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí. 2Gbà mí kí o sì tú mi sílẹ̀ nínú òdodo rẹ;
dẹ etí rẹ sí mi, kí o sì gbà mí. 3Jẹ́ àpáta ààbò mi,
níbi tí èmi lè máa lọ,
pa àṣẹ láti gbà mí,
nítorí ìwọ ni àpáta àti odi agbára mi. 4Gbà mí, Ọlọ́run mi, lọ́wọ́ àwọn olùṣe búburú,
ní ọwọ́ aláìṣòdodo àti ìkà ọkùnrin.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.