Native Bible

Psalms 69:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

àwọn ọmọ ọmọ ọ̀dọ̀ ni yóò máa jogún rẹ̀, àwọn tí ó fẹ́ orúkọ rẹ ni yóò máa gbé inú rẹ̀.

Psalms 69:36 in English

Psalms 69:36 · Berean Standard Bible

The descendants of His servants will inherit it, and those who love His name will settle in it.

Context

34Kí ọ̀run àti ayé yìn ín, òkun àti àwọn tí ń gbé inú rẹ̀, 35nítorí tí Ọlọ́run yóò gba Sioni là yóò sì tún àwọn ìlú Juda wọ̀nyí kọ́. Kí wọn ó lè máa gbé ibẹ̀, kí wọn ó lè máa ní ní ilẹ̀ ìní; 36àwọn ọmọ ọmọ ọ̀dọ̀ ni yóò máa jogún rẹ̀, àwọn tí ó fẹ́ orúkọ rẹ ni yóò máa gbé inú rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.