Saamu 69:30
Psalms 69:30 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi yóò fi orin gbé orúkọ Ọlọ́run ga èmi yóò fi ọpẹ́ gbé orúkọ rẹ̀ ga.
Psalms 69:30 in English
Psalms 69:30 · Berean Standard Bible
I will praise God’s name in song and exalt Him with thanksgiving.
Context
28Jẹ́ kí a yọ wọ́n kúrò nínú ìwé ìyè
kí á má kà wọ́n pẹ̀lú àwọn olódodo. 29Ṣùgbọ́n tálákà àti ẹni-ìkáàánú ni èmí,
Ọlọ́run, jẹ́ kí ìgbàlà rẹ gbé mi lékè. 30Èmi yóò fi orin gbé orúkọ Ọlọ́run ga
èmi yóò fi ọpẹ́ gbé orúkọ rẹ̀ ga. 31Eléyìí tẹ́ Olúwa lọ́rùn ju ọ̀dá màlúù lọ
ju akọ màlúù pẹ̀lú ìwo rẹ̀ àti bàtà rẹ̀. 32Àwọn òtòṣì yóò rí, wọn yóò sì yọ̀:
ẹ̀yin yóò wá Ọlọ́run, ọkàn yín yóò sì wà láààyè!
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.