Native Bible

Psalms 6:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa ti gbọ́ ẹkún mi fún àánú; Olúwa ti gba àdúrà mi.

Psalms 6:9 in English

Psalms 6:9 · Berean Standard Bible

The LORD has heard my cry for mercy; the LORD accepts my prayer.

Context

7Ojú mi di aláìlera pẹ̀lú ìbànújẹ́; wọ́n kùnà nítorí gbogbo ọ̀tá mi. 8Kúrò lọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣe iṣẹ́ ibi, nítorí Olúwa ti gbọ́ igbe mi. 9Olúwa ti gbọ́ ẹkún mi fún àánú; Olúwa ti gba àdúrà mi. 10Gbogbo àwọn ọ̀tá mi lójú yóò tì, wọn yóò sì dààmú; wọn yóò sì yípadà nínú ìtìjú àìròtẹ́lẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.