Saamu 56:1
Psalms 56:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run, nítorí àwọn ènìyàn ń fi ìgbónára lépa mi; ní gbogbo ọjọ́ ni wọn ń kọjú ìjà sí mi, wọn ń ni mi lára.
Psalms 56:1 in English
Psalms 56:1 · Berean Standard Bible
Be merciful to me, O God, for men are hounding me; all day they press their attack.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.