Native Bible

Psalms 48:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayé, Òun ni yóò ṣe amọ̀nà wa títí dè òpin ayé.

Psalms 48:14 in English

Psalms 48:14 · Berean Standard Bible

For this God is our God forever and ever; He will be our guide even till death.*

Context

12Rìn Sioni kiri lọ yíká rẹ̀, ka ilé ìṣọ́ rẹ̀. 13Kíyèsi odi rẹ̀, kíyèsi àwọn ààfin rẹ̀ kí ẹ̀yin lè máa wí fún ìran tí ń bọ̀. 14Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayé, Òun ni yóò ṣe amọ̀nà wa títí dè òpin ayé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.