Native Bible

Psalms 48:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kíyèsi odi rẹ̀, kíyèsi àwọn ààfin rẹ̀ kí ẹ̀yin lè máa wí fún ìran tí ń bọ̀.

Psalms 48:13 in English

Psalms 48:13 · Berean Standard Bible

consider her ramparts, tour her citadels, that you may tell the next generation.

Context

11Jẹ́ kí òkè Sioni kí ó yọ̀ kí inú àwọn ọmọbìnrin Juda kí ó dùn nítorí ìdájọ́ rẹ. 12Rìn Sioni kiri lọ yíká rẹ̀, ka ilé ìṣọ́ rẹ̀. 13Kíyèsi odi rẹ̀, kíyèsi àwọn ààfin rẹ̀ kí ẹ̀yin lè máa wí fún ìran tí ń bọ̀. 14Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayé, Òun ni yóò ṣe amọ̀nà wa títí dè òpin ayé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.