Saamu 44:1
Psalms 44:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
À ti fi etí wa gbọ́, Ọlọ́run; àwọn baba wa tí sọ fún wa ohun tí ìwọ ṣe ní ọjọ́ wọn, ní ọjọ́ pípẹ́ sẹ́yìn.
Psalms 44:1 in English
Psalms 44:1 · Berean Standard Bible
We have heard with our ears, O God; our fathers have told us the work You did in their days, in the days of old.
Context
1À ti fi etí wa gbọ́, Ọlọ́run;
àwọn baba wa tí sọ fún wa
ohun tí ìwọ ṣe ní ọjọ́ wọn,
ní ọjọ́ pípẹ́ sẹ́yìn. 2Ìwọ fi ọwọ́ rẹ lé orílẹ̀-èdè jáde,
Ìwọ sì gbin àwọn baba wa;
ìwọ run àwọn ènìyàn náà
Ìwọ sì mú àwọn baba wa gbilẹ̀. 3Kì í ṣe nípa idà wọn ni wọ́n gba ilẹ̀ náà,
bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe apá wọn ní ó gbà wọ́n bí kò ṣe;
ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ àti, apá rẹ;
àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ̀, nítorí ìwọ fẹ́ wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.