Saamu 25:4
Psalms 25:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Fi ọ̀nà rẹ hàn mí, Olúwa, kọ mi ní ipa tìrẹ;
Psalms 25:4 in English
Psalms 25:4 · Berean Standard Bible
Show me Your ways, O LORD; teach me Your paths.
Context
2Ọlọ́run, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ;
má ṣe jẹ́ kí ojú ó tì mí
má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi ó yọ̀ mí. 3Ẹni tí ó dúró tì ọ́
ojú kì yóò tì í,
àwọn tí ń ṣẹ̀ láìnídìí
ni kí ojú kí ó tì. 4Fi ọ̀nà rẹ hàn mí, Olúwa,
kọ mi ní ipa tìrẹ; 5ṣe amọ̀nà mi nínú òtítọ́ ọ̀ rẹ, kí o sì kọ́ mi,
nítorí ìwọ ni Ọlọ́run ìgbàlà mi;
ìwọ ni mo dúró tì ní gbogbo ọjọ́. 6Rántí, Olúwa àánú àti ìfẹ́ ẹ̀ rẹ̀ ńlá,
torí pé wọ́n ti wà ní ìgbà àtijọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.