Saamu 146:2
Psalms 146:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi yóò yin Olúwa ní gbogbo ayé mi, èmi yóò kọrin ìyìn sí Ọlọ́run, níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láààyè.
Psalms 146:2 in English
Psalms 146:2 · Berean Standard Bible
I will praise the LORD all my life; I will sing praises to my God while I have my being.
Context
1Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.
Fi ìyìn fún Olúwa, ìwọ ọkàn mi. 2Èmi yóò yin Olúwa ní gbogbo ayé mi,
èmi yóò kọrin ìyìn sí Ọlọ́run, níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láààyè. 3Ẹ má ṣe ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú àwọn ọmọ-aládé,
àní, ọmọ ènìyàn,
lọ́wọ́ ẹni tí kò sí ìrànlọ́wọ́. 4Ẹ̀mí rẹ jáde lọ, ó padà sí erùpẹ̀,
ní ọjọ́ náà gan, èrò wọn yóò di òfo.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.