Saamu 145:9
Psalms 145:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa dára sí ẹni gbogbo; ó ní àánú lórí ohun gbogbo tí ó dá.
Psalms 145:9 in English
Psalms 145:9 · Berean Standard Bible
The LORD is good to all; His compassion rests on all He has made.
Context
7Wọn yóò ṣe ìrántí ọ̀pọ̀lọpọ̀
ìwà rere rẹ àti orin ayọ̀ òdodo rẹ. 8Olóore-ọ̀fẹ́ ni Olúwa àti aláàánú
ó lọ́ra láti bínú ó sì ní ìfẹ́ púpọ̀. 9Olúwa dára sí ẹni gbogbo;
ó ní àánú lórí ohun gbogbo tí ó dá. 10Gbogbo ohun tí ìwọ ti dá ni
yóò máa yìn ọ́ Olúwa;
àwọn ẹni mímọ́ yóò máa pòkìkí rẹ. 11Wọn yóò sọ ògo ìjọba rẹ
wọn yóò sì sọ̀rọ̀ agbára rẹ,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.