Native Bible

Psalms 145:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọn yóò sọ ògo ìjọba rẹ wọn yóò sì sọ̀rọ̀ agbára rẹ,

Psalms 145:11 in English

Psalms 145:11 · Berean Standard Bible

They will tell of the glory of Your kingdom and speak of Your might,

Context

9Olúwa dára sí ẹni gbogbo; ó ní àánú lórí ohun gbogbo tí ó dá. 10Gbogbo ohun tí ìwọ ti dá ni yóò máa yìn ọ́ Olúwa; àwọn ẹni mímọ́ yóò máa pòkìkí rẹ. 11Wọn yóò sọ ògo ìjọba rẹ wọn yóò sì sọ̀rọ̀ agbára rẹ, 12kí gbogbo ènìyàn le mọ iṣẹ́ agbára rẹ̀ àti ọláńlá ìjọba rẹ tí ó lógo. 13Ìjọba rẹ ìjọba ayérayé ni, àti ìjọba rẹ wà ní gbogbo ìrandíran.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.