Native Bible

Psalms 136:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àti Ogu, ọba Baṣani; nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.

Psalms 136:20 in English

Psalms 136:20 · Berean Standard Bible

and Og king of Bashan— His loving devotion endures forever.

Context

18Ó sì pa àwọn ọba olókìkí nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 19Sihoni, ọba àwọn ará Amori nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 20Àti Ogu, ọba Baṣani; nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 21Ó sì fi ilẹ̀ wọn fún ni ní ìní, nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 22Ìní fún Israẹli, ìránṣẹ́ rẹ̀, nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.