Saamu 136:22
Psalms 136:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìní fún Israẹli, ìránṣẹ́ rẹ̀, nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Psalms 136:22 in English
Psalms 136:22 · Berean Standard Bible
a heritage to His servant Israel. His loving devotion endures forever.
Context
20Àti Ogu, ọba Baṣani;
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 21Ó sì fi ilẹ̀ wọn fún ni ní ìní,
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 22Ìní fún Israẹli, ìránṣẹ́ rẹ̀,
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 23Ẹni tí ó rántí wa ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀ wa;
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 24Ó sì dá wa ní ìdè lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa;
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.