Saamu 124:3
Psalms 124:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
nígbà náà ni wọn ò bá gbé wà mì láààyè nígbà tí ìbínú wọn ru sí wa,
Psalms 124:3 in English
Psalms 124:3 · Berean Standard Bible
when their anger flared against us, then they would have swallowed us alive,
Context
1“Ìbá má ṣe pé Olúwa tí ó ti wà fún wa,”
kí ni Israẹli kí ó máa wí nísinsin yìí; 2ìbá má ṣe pé Olúwa tó wà ní tiwa,
nígbà tí àwọn ènìyàn gbógun sí wa, 3nígbà náà ni wọn ò bá gbé wà mì láààyè
nígbà tí ìbínú wọn ru sí wa, 4nígbà náà ni omi
wọ̀n-ọn-nì ìbá bò wá mọ́lẹ̀, 5nígbà náà ni agbéraga
omi ìbá borí ọkàn wa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.