Native Bible

Psalms 124:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ìbá má ṣe pé Olúwa tó wà ní tiwa, nígbà tí àwọn ènìyàn gbógun sí wa,

Psalms 124:2 in English

Psalms 124:2 · Berean Standard Bible

if the LORD had not been on our side when men attacked us,

Context

1“Ìbá má ṣe pé Olúwa tí ó ti wà fún wa,” kí ni Israẹli kí ó máa wí nísinsin yìí; 2ìbá má ṣe pé Olúwa tó wà ní tiwa, nígbà tí àwọn ènìyàn gbógun sí wa, 3nígbà náà ni wọn ò bá gbé wà mì láààyè nígbà tí ìbínú wọn ru sí wa, 4nígbà náà ni omi wọ̀n-ọn-nì ìbá bò wá mọ́lẹ̀,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.