Native Bible

Psalms 120:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kí ni kí a fi fún ọ? Àti kí ni kí a túnṣe fún ọ, ìwọ ahọ́n ẹ̀tàn?

Psalms 120:3 in English

Psalms 120:3 · Berean Standard Bible

What will He do to you, and what will be added to you, O deceitful tongue?

Context

1Èmi ké pe Olúwa nínú ìpọ́njú mi, ó sì dá mi lóhùn. 2Gbà mí, Olúwa, kúrò lọ́wọ́ ètè èké àti lọ́wọ́ ahọ́n ẹ̀tàn. 3Kí ni kí a fi fún ọ? Àti kí ni kí a túnṣe fún ọ, ìwọ ahọ́n ẹ̀tàn? 4Òun yóò bá ọ wí pẹ̀lú ọfà mímú ológun, pẹ̀lú ẹ̀yín iná igi ìgbálẹ̀. 5Ègbé ni fún mi tí èmi ṣe àtìpó ní Meṣeki, nítorí èmi gbé nínú àgọ́ ìlú Kedari!

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.