Saamu 119:91
Psalms 119:91 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òfin rẹ dúró di òní nítorí ohun gbogbo ń sìn ọ́.
Psalms 119:91 in English
Psalms 119:91 · Berean Standard Bible
Your ordinances stand to this day,* for all things are servants to You.
Context
89Ọ̀rọ̀ rẹ, Olúwa, títí láé ni;
ó dúró ṣinṣin ní ọ̀run. 90Òtítọ́ rẹ̀ ń lọ dé gbogbo ìran dé ìran;
ìwọ ti dá ayé, ó sì dúró ṣinṣin. 91Òfin rẹ dúró di òní
nítorí ohun gbogbo ń sìn ọ́. 92Bí òfin rẹ̀ kò bá jẹ́ dídùn inú mi,
èmi ìbá ti ṣègbé nínú ìpọ́njú mi. 93Èmi kì yóò gbàgbé ẹ̀kọ́ rẹ láé,
nítorí nípa wọn ni ìwọ ti pa ayé mi mọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.