Saamu 118:14
Psalms 118:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa ni agbára àti orin mi; ó sì di ìgbàlà mi.
Psalms 118:14 in English
Psalms 118:14 · Berean Standard Bible
The LORD is my strength and my song, and He has become my salvation.
Context
12Wọ́n gbá yìn ìn yí mi ká bí oyin,
ṣùgbọ́n wọ́n kú kíákíá bí iná ẹ̀gún;
ní orúkọ Olúwa èmi ké wọn dànù. 13Ìwọ tì mí gidigidi kí n lè ṣubú,
ṣùgbọ́n Olúwa ràn mí lọ́wọ́. 14Olúwa ni agbára àti orin mi;
ó sì di ìgbàlà mi. 15Ohùn ayọ̀ àti ìgbàlà ń bẹ nínú àgọ́ àwọn olódodo:
“Ọwọ́ ọ̀tún Olúwa ń ṣe ohun agbára! 16Ọwọ́ ọ̀tún Olúwa ní a gbéga;
ọwọ́ ọ̀tún Olúwa ń ṣe ohun agbára!”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.