Saamu 113:9
Psalms 113:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó mú àgàn obìnrin gbé inú ilé, àti láti jẹ́ aláyọ̀ ìyá fún àwọn ọmọ rẹ̀. Ẹ yin Olúwa.
Psalms 113:9 in English
Psalms 113:9 · Berean Standard Bible
He settles the barren woman in her home as a joyful mother to her children. Hallelujah!
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.