Native Bible

Psalms 107:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó fi ọ̀nà títọ́ hàn wọ́n sí ìlú tí wọn lè máa gbé.

Psalms 107:7 in English

Psalms 107:7 · Berean Standard Bible

He led them on a straight path to reach a city where they could live.

Context

5Ebi ń pa wọn, òǹgbẹ gbẹ wọ́n, ó sì rẹ ọkàn wọn nínú wọn. 6Ní ìgbà náà, wọ́n kígbe sókè sí Olúwa nínú ìdààmú wọn, ó sì yọ wọ́n kúrò nínú ìrora wọn 7Ó fi ọ̀nà títọ́ hàn wọ́n sí ìlú tí wọn lè máa gbé. 8Ẹ jẹ́ kí wọn máa yin Olúwa nítorí ìṣeun ìfẹ́ rẹ̀ àti nítorí iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ sí àwọn ọmọ ènìyàn, 9nítorí tí ó tẹ́ ìfẹ́ ọkàn lọ́run ó sì fi ìre fún ọkàn tí ebi ń pa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.