Saamu 107:35
Psalms 107:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
O sọ aginjù di adágún omi àti ilẹ̀ gbígbẹ di orísun omi,
Psalms 107:35 in English
Psalms 107:35 · Berean Standard Bible
He turns a desert into pools of water and a dry land into flowing springs.
Context
33Ó sọ odò di aginjù,
àti orísun omi di ilẹ̀ gbígbẹ. 34Ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀
nítorí ìwà búburú àwọn tí ó wà nínú rẹ̀. 35O sọ aginjù di adágún omi àti
ilẹ̀ gbígbẹ di orísun omi, 36níbẹ̀ ó mú ẹni tí ebi ń pa wà,
wọ́n sì pilẹ̀ ibi tí wọn ó máa gbé. 37Wọn fún irúgbìn, wọ́n sì gbin ọgbà àjàrà
tí yóò máa so èso tí ó dára;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.