Saamu 107:33
Psalms 107:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sọ odò di aginjù, àti orísun omi di ilẹ̀ gbígbẹ.
Psalms 107:33 in English
Psalms 107:33 · Berean Standard Bible
He turns rivers into deserts, springs of water into thirsty ground,
Context
31Jẹ́ kí wọn fi ọpẹ́ fún
Olúwa nítorí ìṣeun ìfẹ́ rẹ̀
àti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ fún ọmọ ènìyàn. 32Jẹ́ kí wọn gbé e ga ní àárín àwọn ènìyàn
kí wọn kí ó sì yìn ín ní ìjọ àwọn àgbàgbà. 33Ó sọ odò di aginjù,
àti orísun omi di ilẹ̀ gbígbẹ. 34Ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀
nítorí ìwà búburú àwọn tí ó wà nínú rẹ̀. 35O sọ aginjù di adágún omi àti
ilẹ̀ gbígbẹ di orísun omi,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.