Native Bible

Psalms 106:32 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Níbi omi Meriba, wọ́n bí Ọlọ́run nínú, ohun búburú wá sí orí Mose nítorí wọn.

Psalms 106:32 in English

Psalms 106:32 · Berean Standard Bible

At the waters of Meribah * they angered the LORD, and trouble came to Moses because of them.

Context

30Ṣùgbọ́n Finehasi dìde láti dá sí i, àjàkálẹ̀-ààrùn náà sì dáwọ́ dúró lọ́gán. 31A sì ka èyí sí òdodo fún un àti fún àwọn ìrandíran tí ń bọ̀ 32Níbi omi Meriba, wọ́n bí Ọlọ́run nínú, ohun búburú wá sí orí Mose nítorí wọn. 33Nítorí tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí Ẹ̀mí Ọlọ́run. Ọ̀rọ̀ àìdára sì ti ẹnu Mose wá. 34Wọn kò pa àwọn ènìyàn run gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sọ fún wọn,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.