Saamu 106:31
Psalms 106:31 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
A sì ka èyí sí òdodo fún un àti fún àwọn ìrandíran tí ń bọ̀
Psalms 106:31 in English
Psalms 106:31 · Berean Standard Bible
It was credited to him as righteousness for endless generations to come.
Context
29wọ́n mú Ọlọ́run bínú pẹ̀lú ohun búburú tí wọn ń ṣe
àjàkálẹ̀-ààrùn jáde láàrín wọn. 30Ṣùgbọ́n Finehasi dìde láti dá sí i,
àjàkálẹ̀-ààrùn náà sì dáwọ́ dúró lọ́gán. 31A sì ka èyí sí òdodo fún un àti
fún àwọn ìrandíran tí ń bọ̀ 32Níbi omi Meriba, wọ́n bí Ọlọ́run nínú,
ohun búburú wá sí orí Mose nítorí wọn. 33Nítorí tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí Ẹ̀mí Ọlọ́run.
Ọ̀rọ̀ àìdára sì ti ẹnu Mose wá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.