Saamu 106:20
Psalms 106:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n pa ògo wọn dà sí àwòrán màlúù, tí ń jẹ koríko.
Psalms 106:20 in English
Psalms 106:20 · Berean Standard Bible
They exchanged their Glory * for the image of a grass-eating ox.
Context
18Ọwọ́ iná yọ ní ẹgbẹ́ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀;
iná jo àwọn ènìyàn búburú. 19Ní Horebu wọ́n ṣe ẹgbọrọ màlúù
wọ́n sì sin òrìṣà tí a ṣe láti ara irin. 20Wọ́n pa ògo wọn dà
sí àwòrán màlúù, tí ń jẹ koríko. 21Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run, ẹni tí ó gbà wọ́n
ẹni tí ó ti ṣe ohun ńlá ní Ejibiti, 22iṣẹ́ ìyanu ní ilẹ̀ Hamu
àti ohun ẹ̀rù ni ẹ̀bá Òkun Pupa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.