Saamu 102:21
Psalms 102:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kí a lè sọ orúkọ Olúwa ní Sioni àti ìyìn rẹ̀ ní Jerusalẹmu.
Psalms 102:21 in English
Psalms 102:21 · Berean Standard Bible
that they may proclaim the name of the LORD in Zion and praise Him in Jerusalem,
Context
19“Olúwa wo ilẹ̀ láti òkè mímọ́ rẹ̀ wá
láti ọ̀run wá ni ó bojú wo ayé, 20láti gbọ́ ìrora ará túbú,
láti tú àwọn tí a yàn sí ikú sílẹ̀.” 21Kí a lè sọ orúkọ Olúwa ní Sioni
àti ìyìn rẹ̀ ní Jerusalẹmu. 22Ní ìgbà tí a kó àwọn ènìyàn àti
ìjọba pọ̀ láti máa sìn Olúwa. 23Ní ipa ọ̀nà mi, ó rẹ agbára mi sílẹ̀,
ó gé ọjọ́ mi kúrú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.