Òwe 9:18
Proverbs 9:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ṣùgbọ́n wọn ò funra pé àwọn òkú wà níbẹ̀, pé àwọn àlejò rẹ̀ wà ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀ isà òkú.
Proverbs 9:18 in English
Proverbs 9:18 · Berean Standard Bible
But they do not know that the dead * are there, that her guests are in the depths of Sheol.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.