Òwe 8:4
Proverbs 8:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Sí i yín ẹ̀yin ènìyàn, ní mo ń kígbe pè; mo gbé ohun mi sókè sí gbogbo ènìyàn.
Proverbs 8:4 in English
Proverbs 8:4 · Berean Standard Bible
“To you, O men, I call out, and my cry is to the sons of men.
Context
2Ní ibi gíga ní ẹ̀gbẹ́ ọ̀nà,
ní ìkóríta, ní ó dúró; 3ní ẹgbẹ́ ibodè tí ó wọ ìlú,
ní ẹnu ibodè ni ó ń kígbe sókè: 4“Sí i yín ẹ̀yin ènìyàn, ní mo ń kígbe pè;
mo gbé ohun mi sókè sí gbogbo ènìyàn. 5Ẹ̀yin aláìmọ̀kan, ẹ kọ́gbọ́n;
ẹ̀yin aṣiwèrè, ẹ gba òye. 6Ẹ gbọ́, nítorí tí èmi ó sọ̀rọ̀ ohun iyebíye;
Èmí ṣí ètè mi láti sọ ohun tí ó tọ́,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.