Òwe 8:15
Proverbs 8:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nípasẹ̀ mi ni ọba ń ṣàkóso tí àwọn aláṣẹ sì ń ṣe òfin tí ó dára.
Proverbs 8:15 in English
Proverbs 8:15 · Berean Standard Bible
By me kings reign, and rulers enact just laws;
Context
13Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìkórìíra ibi
mo kórìíra ìgbéraga àti agídí,
ìwà ibi àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn. 14Ìmọ̀ràn àti ọgbọ́n tí ó yè kooro jẹ́ tèmi
mo ní òye àti agbára. 15Nípasẹ̀ mi ni ọba ń ṣàkóso
tí àwọn aláṣẹ sì ń ṣe òfin tí ó dára. 16Nípasẹ̀ mi àwọn ọmọ-aládé ń ṣàkóso,
àti gbogbo ọlọ́lá tí ń ṣàkóso ilẹ̀ ayé. 17Mo fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn mi,
àwọn tí ó sì wá mi rí mi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.