Native Bible

Proverbs 7:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ní ojú fèrèsé ilé è mi mo wo ìta láti ojú fèrèsé.

Proverbs 7:6 in English

Proverbs 7:6 · Berean Standard Bible

For at the window of my house I looked through the lattice.

Context

4Wí fún ọgbọ́n pé, “Ìwọ ni arábìnrin mi,” sì pe òye ní ìbátan rẹ. 5Wọn yóò pa ó mọ́ kúrò lọ́wọ́ obìnrin alágbèrè, kúrò lọ́wọ́ àjèjì obìnrin àti ọ̀rọ̀ ìtànjẹ rẹ̀. 6Ní ojú fèrèsé ilé è mi mo wo ìta láti ojú fèrèsé. 7Mo rí i láàrín àwọn aláìmọ̀kan mo sì kíyèsi láàrín àwọn ọ̀dọ́kùnrin, ọ̀dọ́ kan tí ó ṣe aláìgbọ́n. 8Ó ń lọ ní pópónà ní tòsí i ilé alágbèrè obìnrin náà, ó ń rìn lọ sí ọ̀nà ilé e rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.