Native Bible

Proverbs 6:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kò ní olùdarí, kò sí alábojútó tàbí ọba,

Proverbs 6:7 in English

Proverbs 6:7 · Berean Standard Bible

Without a commander, without an overseer or ruler,

Context

5Gba ara rẹ sílẹ̀, bí abo èsúró kúrò lọ́wọ́ ọdẹ, bí ẹyẹ kúrò nínú okùn àwọn pẹyẹpẹyẹ. 6Tọ èèrà lọ, ìwọ ọ̀lẹ; kíyèsi ìṣe rẹ̀, kí o sì gbọ́n! 7Kò ní olùdarí, kò sí alábojútó tàbí ọba, 8síbẹ̀, a kó ìpèsè rẹ̀ jọ ní àsìkò òjò yóò sì kó oúnjẹ rẹ̀ jọ ní àsìkò ìkórè. 9Yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò dùbúlẹ̀, ìwọ ọ̀lẹ? Nígbà wo ni ìwọ yóò jí kúrò lójú oorun rẹ?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.