Native Bible

Proverbs 31:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ta ni ó le rí aya oníwà rere? Ó níye lórí ju iyùn lọ.

Proverbs 31:10 in English

Proverbs 31:10 · Berean Standard Bible

A wife * of noble character, who can find? She is far more precious than rubies.

Context

8“Sọ̀rọ̀ lórúkọ àwọn tí kò le sọ̀rọ̀ fúnra wọn fún ẹ̀tọ́ àwọn ẹni tí ń parun. 9Sọ̀rọ̀ kí o sì ṣe ìdájọ́ àìṣègbè jà fún ẹ̀tọ́ àwọn tálákà àti aláìní.” 10Ta ni ó le rí aya oníwà rere? Ó níye lórí ju iyùn lọ. 11Ọkọ rẹ̀ ní ìgbẹ́kẹ̀lé púpọ̀ nínú rẹ̀ kò sì ṣí ìwà rere tí kò pé lọ́wọ́ rẹ̀. 12Ire ní ó ń ṣe fún un, kì í ṣe ibi ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.