Òwe 30:28
Proverbs 30:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọmọnílé fi ọwọ́ rẹ̀ dì mú, síbẹ̀ a ń rí i ní ààfin ọba.
Proverbs 30:28 in English
Proverbs 30:28 · Berean Standard Bible
and the lizard can be caught in one’s hands, yet it is found in the palaces of kings.
Context
26Ehoro jẹ́ aláìlágbára ẹ̀dá;
síbẹ̀ wọ́n ń ṣe ihò wọn sí ibi pálapàla àpáta; 27àwọn eṣú kò ní ọba,
síbẹ̀ gbogbo wọ́n ń jáde lọ ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ 28Ọmọnílé fi ọwọ́ rẹ̀ dì mú,
síbẹ̀ a ń rí i ní ààfin ọba. 29“Àwọn ohun mẹ́ta ní ń bẹ tí ń rìn rere,
ohun mẹ́rin ni ó dára púpọ̀ ní ìrìn rírìn: 30Kìnnìún, alágbára láàrín ẹranko tí kì í sá fún ohunkóhun
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.