Òwe 24:7
Proverbs 24:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọgbọ́n ga ju fún aṣiwèrè àti gbọ̀ngàn ìlú níbi ibodè kò ní ohun tí yóò wí.
Proverbs 24:7 in English
Proverbs 24:7 · Berean Standard Bible
Wisdom is too high for a fool; he does not open his mouth in the meeting place.
Context
5Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbára púpọ̀,
ènìyàn tí ó ní ìmọ̀ sì ń ní agbára sí i. 6Láti jagun, ó nílò ìtọ́sọ́nà:
nínú ìṣẹ́gun ni ọ̀pọ̀ onígbìmọ̀. 7Ọgbọ́n ga ju fún aṣiwèrè
àti gbọ̀ngàn ìlú níbi ibodè kò ní ohun tí yóò wí. 8Ẹni tí ń pète ibi
ni a ó mọ̀ bí ènìyàn ibi. 9Ète òmùgọ̀ ènìyàn jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀,
àwọn ènìyàn sì kórìíra ẹlẹ́gàn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.