Òwe 2:11
Proverbs 2:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìmòye yóò pa ọ mọ́ òye yóò sì máa ṣọ́ ọ.
Proverbs 2:11 in English
Proverbs 2:11 · Berean Standard Bible
Discretion will watch over you, and understanding will guard you,
Context
9Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ òdodo àti ìdájọ́,
àti àìṣègbè—gbogbo ipa ọ̀nà rere. 10Nítorí ọgbọ́n yóò wọ inú ọkàn rẹ
ìmọ̀ yóò sì jẹ́ ìtura fún ọkàn rẹ. 11Ìmòye yóò pa ọ mọ́
òye yóò sì máa ṣọ́ ọ. 12Ọgbọ́n yóò gbà ọ́ là kúrò ní ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú,
lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn tí ọrọ̀ ọ wọn jẹ́ àyídáyidà, 13ẹni tí ó kúrò ní ọ̀nà ìdúró ṣinṣin
láti rìn ní ọ̀nà tí ó ṣókùnkùn,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.