Òwe 1:16
Proverbs 1:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí ẹsẹ̀ wọn ń sáré sí ẹ̀ṣẹ̀, wọ́n yára láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.
Proverbs 1:16 in English
Proverbs 1:16 · Berean Standard Bible
For their feet run to evil, and they are swift to shed blood.
Context
14da ìpín rẹ pọ̀ mọ́ àárín wa,
a ó sì jọ pawó sínú àpò kan náà,” 15ọmọ mi, má ṣe bá wọn lọ,
má ṣe rìn ní ojú ọ̀nà wọn. 16Nítorí ẹsẹ̀ wọn ń sáré sí ẹ̀ṣẹ̀,
wọ́n yára láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀. 17Wàhálà asán ni kí ènìyàn máa dẹ àwọ̀n sílẹ̀,
ní ojú ẹyẹ! 18Àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ń lúgọ fún ẹ̀jẹ̀ ara wọn.
Ara wọn ni wọ́n ń dá lọ́nà.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.