Numeri 7:16
Numbers 7:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,
Numbers 7:16 in English
Numbers 7:16 · Berean Standard Bible
one male goat for a sin offering;
Context
14àwo wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣékélì mẹ́wàá tí ó kún fún tùràrí; 15ọ̀dọ́ akọ màlúù kan, àgbò kan, akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun, 16akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, 17akọ màlúù méjì, àgbò márùn-ún, òbúkọ ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà.
Wọ̀nyí ni ọrẹ Nahiṣoni ọmọ Amminadabu. 18Ní ọjọ́ kejì ni Netaneli ọmọ Suari olórí àwọn ọmọ Isakari mú ọrẹ tirẹ̀ wá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.