Native Bible

Numbers 16:43 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà náà ni Mose àti Aaroni lọ síwájú àgọ́ ìpàdé,

Numbers 16:43 in English

Numbers 16:43 · Berean Standard Bible

Then Moses and Aaron went to the front of the Tent of Meeting,

Context

41Ní ọjọ́ kejì gbogbo ìjọ àwọn ọmọ Israẹli kùn sí Mose àti Aaroni pé, “Ẹ ti pa àwọn ènìyàn Olúwa.” 42Ṣùgbọ́n nígbà tí gbogbo ìjọ ènìyàn péjọ lòdì sí Mose àti Aaroni, níwájú àgọ́ ìpàdé, lójijì ni ìkùùkuu bolẹ̀, ògo Olúwa sì fi ara hàn. 43Nígbà náà ni Mose àti Aaroni lọ síwájú àgọ́ ìpàdé, 44Olúwa sì sọ fún Mose pé, 45“Yàgò kúrò láàrín ìjọ ènìyàn yìí, kí ń ba le run wọ́n ní ìṣẹ́jú kan.” Wọ́n sì dojúbolẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.