Numeri 10:15
Numbers 10:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Netaneli ọmọ Suari ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Isakari;
Numbers 10:15 in English
Numbers 10:15 · Berean Standard Bible
Nethanel son of Zuar was over the division of the tribe of Issachar,
Context
13Wọ́n gbéra nígbà àkọ́kọ́ yìí nípa àṣẹ Olúwa láti ẹnu Mose. 14Àwọn ìpín ti ibùdó Juda ló kọ́kọ́ gbéra tẹ̀lé wọn lábẹ́ ogun wọn Nahiṣoni ọmọ Amminadabu ni ọ̀gágun wọn. 15Netaneli ọmọ Suari ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Isakari; 16Eliabu ọmọ Heloni ni ọ̀gágun ni ìpín ti ẹ̀yà Sebuluni. 17Nígbà náà ni wọ́n sọ tabanaku kalẹ̀ àwọn ọmọ Gerṣoni àti Merari tó gbé àgọ́ sì gbéra.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.